Éfésù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pé, àwọn aláìkọlà jẹ́ àjùmọ̀jogún àti ẹ̀yà ara kan náà, àti alábápín ìlérí nínú Kírísítì Jésù nípa ìyìn rere;

Éfésù 3

Éfésù 3:1-7