Éfésù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú rẹ̀ ni àwa ni ìràpadà wa nípa ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run

Éfésù 1

Éfésù 1:2-10