Éfésù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìdí èyí, nígbà tí mo ti gbúro ìgbàgbọ́ ti ń bẹ láàárin yín nínú Jésù Olúwa, àti ìfẹ́ yín sí gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́.

Éfésù 1

Éfésù 1:11-23