Éfésù 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú rẹ̀ ni a yàn wá fẹ́ lẹ́hìn tí ó ti yàn wá tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìpinu ẹni tí ń ṣiṣẹ́ ohun gbogbo ní ìbámu ìfẹ́ rẹ̀,

Éfésù 1

Éfésù 1:8-19