Deutarónómì 4:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ti fi ojú ara yín rí ohun tí Olúwa ṣe ní Báálí-Péórì. Olúwa Ọlọ́run yín run gbogbo àwọn tí ó tẹ̀lé òrìṣà Báálì ti Péórì kúrò ní àárin yín.

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:1-5