Deutarónómì 34:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣúà ọmọ Núnì kún fún ẹ̀mí ọgbọ́n nítorí Móṣè ti gbọ́wọ́ ọ rẹ̀ lée lórí. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì fetí sí i wọ́n sì ṣe ohun tí Ọlọ́run ti pa láṣẹ fún Mósè.

Deutarónómì 34

Deutarónómì 34:1-11