Deutarónómì 33:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni ọba lórí Jéṣúrúnìní ìgbà tí olórí àwọn ènìyàn péjọ pọ̀,pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:3-14