Ísírẹ́lì nìkan yóò jòkòó ní àlàáfíà,oríṣun Jákọ́bù nìkanní ilẹ̀ ọkà àti ti ọtí wáìnì,níbi tí ọ̀run ti ń ṣẹ ìrì sílẹ̀.