“Kò sí ẹlòmíràn bí Ọlọ́run Jéṣúrúnì,ẹni tí ń gun ọ̀run fún ìrànlọ́wọ́ rẹàti ní ojú ọ̀run nínú ọlá ńlá rẹ̀.