Deutarónómì 33:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti Ṣébúlúnì ó wí pé:“Yọ̀ Sébúlúnì, ní ti ìjáde lọ rẹ,àti ìwọ Ísákárì, nínú àgọ́ rẹ.

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:17-26