Deutarónómì 33:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bù sí ohun ìní rẹ̀, Olúwa,kí o sì tẹ́wọ́gba iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.Lu ẹgbẹ́ àwọn tí ó dìde sí i;kí wọn kí ó má ṣe dìde mọ́.”

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:6-19