Deutarónómì 32:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n rúbọ sí iwin búburú, tí kì í ṣe Ọlọ́run,ọlọ́run tí wọn kò mọ̀ rí,ọlọ́run tí ó sẹ̀sẹ̀ farahàn láìpẹ́,ọlọ́run tí àwọn baba yín kò bẹ̀rù.

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:8-22