Deutarónómì 30:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ní ọ̀run, tí ìwọ kò bá fi wí pé, “Ta ni yóò gòkè lọ sí ọ̀run fún wa, tí yóò sì mú wa fún wa, kí àwa lè gbọ́, kí a sì le ṣe é?”

Deutarónómì 30

Deutarónómì 30:5-18