Deutarónómì 28:66 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò gbé ní ìdádúró ṣinṣin, kún fún ìbẹ̀rù-bojo lọ́sàn án àti lóru, bẹ́ẹ̀ kọ́ láé ni ìwọ yóò rí i ní àrídájú wíwà láyé rẹ.

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:64-68