Deutarónómì 28:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn jẹ́jẹ́ àti onímọ̀ jùlọ kò ní ní àánú fún arákùnrin ara rẹ̀ tàbí ìyàwó tí ó fẹ́ràn tàbí àwọn ọmọ rẹ̀ tí o wà láàyè,

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:50-64