Deutarónómì 28:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò yí òjò ilẹ̀ rẹ sí eekuru ẹ̀tù ìbọn yóò sì wá sílẹ̀ láti ojú ọ̀run títí tí yóò fi pa ọ́ run.

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:23-27