Deutarónómì 28:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègún ni fún ọ nígbà tí o bá wọlé ègún sì ni fún ọ nígbà tí ìwọ bá jáde.

Deutarónómì 28

Deutarónómì 28:10-25