Deutarónómì 27:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó dùbúlẹ̀ pẹ̀lú ìyàwó baba rẹ̀, nítorí ó ti dójúti ibùsùn baba rẹ̀.”Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Deutarónómì 27

Deutarónómì 27:11-26