Deutarónómì 25:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọkùnrin tí ó bá kọ́ bí ni yóò máa jẹ́ orúkọ arákùnrin rẹ̀ tí ó kú náà, kí orúkọ rẹ̀ má baá parẹ́ ní Ísírẹ́lì.

Deutarónómì 25

Deutarónómì 25:4-11