Deutarónómì 25:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe ní oríṣìí ìtẹ̀wọ̀n méjì tó yàtọ̀ sí ara wọn nínú àpò rẹ: ọ̀kan wíwo àti ọ̀kan fífúyẹ́.

Deutarónómì 25

Deutarónómì 25:10-19