Deutarónómì 24:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

San owó iṣẹ́ rẹ̀ ní ọjọ́ kan náà kí ó tó di àṣàálẹ́, nítorí ó jẹ́ talákà, ó sì gbẹ́kẹ̀lé e bí kò ṣe bẹ́ẹ̀ ó lè képe Olúwa sí ọ, o sì máa gba ìdálẹ́bi ẹ̀ṣẹ̀.

Deutarónómì 24

Deutarónómì 24:14-16