Deutarónómì 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì wí pé, “Ẹ dìde, kí ẹ sì la àfonífojì Sérádì kọjá.” Bẹ́ẹ̀ ni a la àfonífojì náà kọjá.

Deutarónómì 2

Deutarónómì 2:4-14