Deutarónómì 14:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ Olúwa Ọlọ́run yín ni ẹ̀yin jẹ́: nítorí náà, ẹ má ṣe ya ara yín ní abẹ. Ẹ má ṣe gé irun iwájú orí i yín nítorí òkú.

Deutarónómì 14

Deutarónómì 14:1-7