Dáníẹ́lì 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa ti ṣẹ̀, a sì ti ṣe búburú. Àwa ti hu ìwà búburú, a sì ti ṣe ọ̀tẹ̀, a ti yí padà kúrò nínú àwọn àṣẹ àti àwọn ìlànà rẹ̀.

Dáníẹ́lì 9

Dáníẹ́lì 9:1-10