Àwọn Hébérù 7:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n òun, nítorí tí o wà títí láé, ó ní oyè àlùfáà tí a kò lè rọ̀ nípò.

Àwọn Hébérù 7

Àwọn Hébérù 7:22-28