Àwọn Hébérù 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe gbàgbé láti máa ṣe àléjò; nítorí pé nípa bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlòmíràn ṣe àwọn áńgẹ́lì ní àlejò láìmọ̀.

Àwọn Hébérù 13

Àwọn Hébérù 13:1-11