Àwọn Hébérù 12:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o má bá à si àgbérè kan tàbí aláìwà-bí-Ọlọ́run bi Èsau, ẹni tí o titorí òkèlè oúnjẹ kan ta ogún ìbí rẹ̀.

Àwọn Hébérù 12

Àwọn Hébérù 12:12-25