Àwọn Hébérù 11:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Ọlọ́run ti pèsè ohun tí o dárajù sílẹ̀ fún wa, pé láìsí wa, kí a má ṣe wọn pé.

Àwọn Hébérù 11

Àwọn Hébérù 11:35-40