Àwọn Hébérù 11:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sọ wọ́n ni òkúta, a fi ayùn rẹ́ wọn sì méjì, a dán wọn wò a fi idà pa wọn: wọn rìn kákiri nínú àwọ àgùntàn àti nínú àwọ ewúrẹ́; wọn di aláìní, olupọ́njú, ẹni tí a ń da lóró;

Àwọn Hébérù 11

Àwọn Hébérù 11:30-40