Àwọn Hébérù 11:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èwo ni èmi o sì tún máa wí sí i? Nítorí pé ìgbà yóò kùnà fún mú láti sọ ti Gídíónì, àti Bárákì, àti Sámsónì, àti Jẹftà; àti Dáfídì, àti Sámúẹ́lì, àti ti àwọn wòlíì:

Àwọn Hébérù 11

Àwọn Hébérù 11:22-40