“Àbá ẹyin ọmọ Ísírẹ́lìkò ha dàbí àwọn ọmọ Kúsì sí mi?”ni Olúwa wí.“Èmi kò ha ti mú Ísírẹ́lì gòkè láti ilẹ̀ Éjíbítì jáde wáàti àwọn Fílístínì láti ilẹ̀ Káfítórìàti àwọn Árámú láti kírì?