“Ní ọjọ́ náà ní Èmi yóò gbéàgọ́ Dáfídì tí ó wó róÈmi yóò mọ odi rẹ̀ tí ó wóÈmi yóò sì sọ ahoro rẹ̀ di ìlúÈmi yóò sì kọ bí ó ti wà tẹ́lẹ̀