Ámósì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà nísinsin yìí, gbọ ọ̀rọ̀ Olúwa. Ìwọ wí pé,“ ‘Má ṣe sọ àṣọtẹ́lẹ̀ sí Ísírẹ́lìMá ṣì ṣe wàásù sí ilé Ísáákì.’

Ámósì 7

Ámósì 7:6-17