Ámósì 5:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ìwọ ilé Ísírẹ́lì, ìpohùnréré ẹkún tí mo ṣe nípa rẹ:

2. “Wúndíá Ísírẹ́lì ṣubúláì kò sì le padà dìdeó di ẹni ìkọ̀tì ní ilẹ̀ rẹ̀kò sí ẹni tí yóò gbé e nàró.”

Ámósì 5