Ámósì 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹ mú ọrẹ́ ìdúpẹ́ ìyẹ̀fun tí a sunkí ẹ sì mú ọrẹ àtinúwálọ fi wọ́n yagàn, ẹ̀yin ènìyàn Ísírẹ́lì,nítorí èyí ni ẹ fẹ́ láti ṣe,”ni Olúwa Ọlọ́run wí.

Ámósì 4

Ámósì 4:1-7