Àìsáyà 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò dúró de Olúwa,ẹni tí ó ń fi ojú rẹ̀ pamọ́ fún ilé Jákọ́bù.Mo fi ìgbẹ́kẹ̀lé mi sínú rẹ.

Àìsáyà 8

Àìsáyà 8:12-19