Àìsáyà 66:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ohun tí Olúwa wí nìyìí:“Ọ̀run ni ìtẹ́ mi,ayé sì ni àpótí ìtìṣẹ mi,Níbo ni ilé tí ẹ ó kọ́ fún mi wà?Níbo ní ibi ìsinmi mi yóò gbé wà?

2. Kì í ha á ṣe ọwọ́ mi ló tí ṣe nǹkan wọ̀nyí,bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì wà?”ni Olúwa wí.“Eléyìí ni ẹni tí mo kà sí:ẹni náà tí ó rẹrarẹ̀ sílẹ̀ tí ó sì kẹ́dùn ní ọkàn rẹ̀,tí ó sì wárìrì nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ mi.

Àìsáyà 66