Àìsáyà 52:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́tísílẹ̀! Àwọn olùṣọ́ rẹ gbé ohùn wọn ṣókèwọ́n kígbe papọ̀ fún ayọ̀.Nígbà tí Olúwa padà sí Ṣíhónì,wọn yóò rí i pẹ̀lú ojúu wọn.

Àìsáyà 52

Àìsáyà 52:3-15