Àìsáyà 52:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyèsí i, ìránṣẹ́ mi yóò hùwà ọlọgbọ́n;òun ni a ó gbé ṣókè tí a ó sì gbégaa ó sì gbé e lékè gidigidi.

Àìsáyà 52

Àìsáyà 52:4-15