Àìsáyà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti sọ ọ́ sími létí“Ó dájú pé àwọn ilé ńlá ńláyóò di ahoro, àwọn ilé dára dára yóò wà láìní olùgbé.

Àìsáyà 5

Àìsáyà 5:1-14