Àìsáyà 5:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò rẹ ẹnìkankan nínú wọn, tàbí kí ó kọṣẹ̀.Ẹnikẹ́ni ò tòògbé tàbí sùn;Ìgbànú ẹnìkankan ò dẹ̀ ní ìbàdí i rẹ̀,okùn sálúbàtà kan ò já.

Àìsáyà 5

Àìsáyà 5:26-30