Àìsáyà 5:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún àwọn tí ń pe ibi ní rere, àti rere ní ibi,tí ń fi òkùnkùn ṣe ìmọ́lẹ̀ àti ìmọ́lẹ̀ ṣe òkunkun,tí ń fi ìkorò ṣe adùn àti adùn ṣe ìkorò.

Àìsáyà 5

Àìsáyà 5:13-22