Àìsáyà 46:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n bẹ̀rẹ̀ wọ́n sì foríbalẹ̀ papọ̀;wọn kò lè gba ẹrù náà,àwọn pẹ̀lú ni a kó lọ ní ìgbèkùn.

Àìsáyà 46

Àìsáyà 46:1-7