Àìsáyà 45:24-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Wọn yóò sọ ní ti èmi, ‘Nínú Olúwa nìkan niòdodo àti agbára wà.’ ”Gbogbo àwọn tí ó ti bínú sí;yóò wá sọ́dọ̀ rẹ̀ a ó sì dójú tì wọn.

25. Ṣùgbọ́n nínú Olúwa gbogbo àwọn ìran Ísírẹ́lìni a ó rí ní òdodo, a o sì gbé wọn ga.

Àìsáyà 45