Àìsáyà 42:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìránṣẹ́ mi nìyìí, ẹni tí mo gbéró,àyànfẹ́ mi nínú ẹni tí mo láyọ̀;Èmi yóò fi Ẹ̀mí mi sínú rẹ̀òun yóò sì mú ìdájọ́ wá sórí àwọn orílẹ̀ èdè.

Àìsáyà 42

Àìsáyà 42:1-5