Àìsáyà 41:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ dákẹ́ jẹ́ ẹ́ níwájúù mi ẹ̀yin erékùṣù!Jẹ́ kí àwọn orílẹ̀ èdè tún agbára wọn ṣe!Jẹ́ kí wọn wá ṣíwájú kí wọn sọ̀rọ̀:Jẹ́ kí a pàdé pọ̀ ní ibi ìdájọ́.

Àìsáyà 41

Àìsáyà 41:1-10