Àìsáyà 40:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti ère, oníṣọ̀nà ni ó dà á,ti alágbẹ̀dẹ wúrà sì fi wúrà bò ótí a sì ṣe ẹ̀wọ̀n ọ̀nà sílífà fún un.

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:11-24