Àìsáyà 39:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà wòlíì Àìṣáyà lọ sí ọ̀dọ̀ Heṣekáyà ọba ó sì béèrè pé, “Kí ni àwọn ènìyàn wọ̀nyí wí, níbo ni wọ́n sì ti wá?”“Láti ilẹ̀ jínjìnnà,” ni èsì Heṣekáyà. “Wọ́n wá sọ́dọ̀ mi láti Bábílónì.”

Àìsáyà 39

Àìsáyà 39:1-8