Àìsáyà 38:21-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Àìṣáyà ti sọ pé, “Pèṣè ìsù (ohun gbígbóná tí a dì mọ́ ojú egbò) kí o sì fi sí ojú oówo náà, òun yóò sì gbádùn.”

22. Heṣekáyà ti sọ pé, “Kí ni yóò jẹ́ àmì pé èmi yóò gòkè lọ sí tẹ́ḿpìlì Olúwa?”

Àìsáyà 38