Àìsáyà 33:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkógun rẹ, ìwọ orílẹ̀ èdè ni a kórègẹ́gẹ́ bí i ti ọ̀dọ́ eṣú;gẹ́gẹ́ bí àkójọpọ̀ eṣú, àwọn ènìyàn bọ́ lù ú.

Àìsáyà 33

Àìsáyà 33:1-10